Album

Sola Allyson – Imisi | [Album + Mp3 Download]

Sola Allyson Imisi Album Zip Download

Renowned contemporary worship music minister Sola Allyson, popularly known in the Yoruba speaking region, the western part of Nigeria. Minister Sola Allyson releases a brand-new project, which serves as her tenth album so far in the gospel music ministries. Her tenth album is Titled IMISI, a beautiful Yoruba word, which maybe interpreted as Inspiration.

TRACK LIST DOWNLOAD 👇

  1. Sola Allyson – IMISI
  2. Sola Allyson – IWO NIKAN
  3. Sola Allyson – MO GB’OLA WA
  4. Sola Allyson – ASISE O SI
  5. Sola Allyson – IRIN AYANMO
  6. Sola Allyson – DARI MI
  7. Sola Allyson – ASE OLA
  8. Sola Allyson – IDUPE

DOWNLOAD IMISI ZIP FILE HERE

Music minister Sola Allyson is best known for singing in her mother’s tongue and a little blend of English language. Most of her songs are always powerful and impactful, even if she is singing in other languages beside the Yoruba language as she believes she was sent to her people.

Let me take you through her previous albums: In the year 2021 she released Isodotun which is still making impacts up till today. In 2019 minister Sola Allyson dropped ÌRÌ, a beautiful album that i can’t personally forget. To take you further, she released Imuse in 2018 and this album was massively successful. Ope was dropped in 2015. Ire was also one of her project back then in 2014 And Im’oore too in 2014, as EP as well as this EP titled Adun in 2014. Finally, She came into limelight with the hit single Eji Owuro (2003), which was the soundtrack album for a film of the same title. After Eji Owuro, she released other albums like Gbeje F’ori in 2005. This year album, IMISI is gonna be more transforming and glorious, so get set for a change of your story. IMISI is available on all digital platforms now.

sola allyson new album 2022

shola allyson imisi album download

sola allyson imisi mp3 download

sola allyson new album 2022

shola allyson imisi album download

sola allyson imisi mp3 download

Sola Allyson Imisi Album Zip Download

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 12
Inúnibíni sí ìjọ

1 Ní àkókò náà Hẹrọdu ọba bẹ̀rẹ̀ sí ṣe inúnibíni sí àwọn kan ninu ìjọ. 2Ó bẹ́ Jakọbu arakunrin Johanu lórí.

3 Nígbà tí ó rí i pé ó dùn mọ́ àwọn Juu, ó bá tún mú Peteru náà. Àkókò náà ni Àjọ̀dún Àìwúkàrà.

4 Ó bá mú Peteru ó tì í mọ́lé. Ó fi í lé àwọn ọ̀wọ́ ọmọ-ogun mẹrin lọ́wọ́ láti máa ṣọ́ ọ; (ọmọ-ogun mẹrin ni ó wà ní ọ̀wọ́ kọ̀ọ̀kan). Hẹrọdu fẹ́ mú Peteru wá siwaju gbogbo eniyan fún ìdájọ́ lẹ́yìn Àjọ̀dún Ìrékọjá.

5 Wọ́n bá sọ Peteru sẹ́wọ̀n, ṣugbọn gbogbo ìjọ ń fi tọkàntọkàn gbadura sí Ọlọrun nítorí rẹ̀.
Peteru Bọ́ lẹ́wọ̀n

6 Ní òru, mọ́jú ọjọ́ tí Hẹrọdu ìbá mú Peteru wá fún ìdájọ́, Peteru sùn láàrin àwọn ọmọ-ogun meji, wọ́n fi ẹ̀wọ̀n meji dè é; àwọn ọmọ-ogun kan sì tún wà lẹ́nu ọ̀nà, tí wọn ń ṣọ́nà.

7 Angẹli Oluwa kan bá yọ dé, ìmọ́lẹ̀ sì tàn ninu ilé náà. Angẹli náà bá rọra lu Peteru lẹ́gbẹ̀ẹ́, ó jí i, ó ní, “Dìde kíá.” Àwọn ẹ̀wọ̀n tí wọ́n fi de Peteru bá yọ bọ́ kúrò ní ọwọ́ rẹ̀,

8 Angẹli náà sọ fún un pé, “Di ìgbànú rẹ, sì wọ sálúbàtà rẹ.” Peteru bá ṣe bí angẹli náà ti wí. Angẹli yìí tún sọ fún un pé, “Da aṣọ rẹ bora, kí o máa tẹ̀lé mi.”

9 Ni Peteru bá tẹ̀lé e jáde. Kò mọ̀ pé òtítọ́ ni ohun tí ó ti ọwọ́ angẹli náà ṣẹlẹ̀, ó ṣebí àlá ni.

10 Wọ́n kọjá ẹ̀ṣọ́ kinni ati ekeji, wọ́n wá dé ẹnu ọ̀nà ńlá onírin tí ó jáde sinu ìlú. Fúnra ìlẹ̀kùn yìí ni ó ṣí sílẹ̀ fún wọn. Wọ́n bá jáde sí ojú ọ̀nà kan. Lójú kan náà, angẹli bá rá mọ́ Peteru lójú.

11 Ojú Peteru wá wálẹ̀. Ó ní, “Mo wá mọ̀ nítòótọ́ pé Oluwa ni ó rán angẹli rẹ̀ láti gbà mí lọ́wọ́ Hẹrọdu, ati láti yọ mí kúrò ninu ohun gbogbo tí àwọn Juu ti ń retí.”

12 Nígbà tí ó rí ohun tí ó ṣẹlẹ̀, ó lọ sí ilé Maria ìyá Johanu tí àdàpè rẹ̀ ń jẹ́ Maku. Ọpọlọpọ eniyan ni ó péjọ sibẹ tí wọn ń gbadura.

13 Nígbà tí Peteru kan ìlẹ̀kùn tí ó wà lójúde, ọdọmọbinrin kan tí ń jẹ́ Roda wá láti ṣí i.

14 Nígbà tí ó gbọ́ ohùn Peteru, inú rẹ̀ dùn tóbẹ́ẹ̀ tí kò fi dúró ṣí ìlẹ̀kùn; ṣugbọn ó sáré lọ sinu ilé, ó lọ sọ pé Peteru wà lóde lẹ́nu ọ̀nà.

15 Wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí bú u pé, “Orí rẹ dàrú!” Ṣugbọn ó ṣá tẹnumọ́ ọn pé bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ rí. Wọ́n wá sọ pé, “A jẹ́ pé angẹli rẹ̀ ni!”

16 Ṣugbọn Peteru tún ń kanlẹ̀kùn. Nígbà tí wọ́n ṣí i, tí wọ́n rí i, ẹnu yà wọ́n. 17Ó bá fi ọwọ́ ṣe àmì sí wọn kí wọ́n dákẹ́; ó ròyìn fún wọn bí Oluwa ti ṣe mú òun jáde kúrò lẹ́wọ̀n. Ó ní kí wọn ròyìn ohun tí ó ṣẹlẹ̀ fún Jakọbu ati fún àwọn arakunrin yòókù. Ó bá jáde, ó lọ sí ibòmíràn.


Join our WhatsApp GROUP or TELEGRAM CHANNEL for instant updates

Leave a Reply

Back to top button

Adblock Detected

Please turnoff your browser's Ad Blocker