Music Video

Download Mp3 Mr Gbera ftALASEYORI – Iru Eriri

Download Mp3 Mr Gbera ft ALASEYORI
Download Mp3 Mr Gbera ft ALASEYORI

Powerful Live song tagged Iriri, original song by Mr. Gbera featuring Adeyinka Alaseyori


DOWNLOAD MP3

Iru Iriri Lyrics ft Adeyinka Alaseyori

Eyi to jababara fun won
sebohun lofi sara fun wo
Iru iriri ti mori gba won kori
Sugbon anu ti morigba woko ri gba

Ohun gbogbo to jababara fun won
sebohun lofi sara fun wo
Ohun toje ipalara fun won
ara irelofi jasi femi
tori moranugba ni

Ohun to lakoja to fa eri
lofa iku opolopo
oje dupe

Ona to hun lo to nmu onje wale
lomu opo lo orun oje dupe
Ona ofun re oda ona iku
oje dupe
Omo tori gbedani ohun logba emi opolopo oje dupe

Iru iriri ti mori gba la won kori
Sugbon anu ti morigba woko ri gba

Iru iriri ti mori gba la won kori
Sugbon anu ti morigba woko ri gba

Orisirisi iriri lohun sele
Aimoye nkan ta ogbori losele
Gbogbo orile ede ohun be ni titi

Iru iriri ti mori gba la won kori
Sugbon anu ti morigba woko ri gba


Join our WhatsApp GROUP or TELEGRAM CHANNEL for instant updates

Leave a Reply

Back to top button

Adblock Detected

Please turnoff your browser's Ad Blocker