Music Video

Bugbe re ti lewa to MP3 Download

Bugbe re ti lewa to MP3 Download
Bugbe re ti lewa to MP3 Download

DOWNLOAD MP3

Yoruba Hymn APA 237 – Bugbe Re ti l’ewa to
APA 237

1. ’Bugbe Re ti l’ewa to!
N’ ile ’mole at’ ife;
Bugbe Re ti l’ewa to!
Laiye ese at’ osi;
Okan mi nfa nitoto
Fun idapo enia Re,
Fun imole oju Re,
Fun ekun Re, Olorun.

2. Ayo ba awon eiye,
Ti nfo yi pepe Re ka;
Ayo okan t’o simi
Laiya Baba l’o poju!
Gege b’adaba Noa,
Ti ko r’ibi simi le,
Nwon pada sodo Baba,
Nwon si nyo titi aiye.

3. Nwon ko simi iyin won,
Ninu aiye osi yi;
Omi nsun ni aginju,
Manna nt’orun wa fun won;
Nwon nlo lat’ ipa de ’pa,
Titi nwon fi yo si O;
Nwon si wole l’ese Re,
T’o mu won la ewu ja.

4. Baba, je ki njere be,
S’amona mi laiye yi;
F’ ore-ofe pa mi mo,
Fun mi l’ aye lodo Re:
Iwo l’ Orun at’ Asa,
To okan isina mi;
Iwo l’ Orisun ore,
Ro ojo re sori mi, Amin.


Join our WhatsApp GROUP or TELEGRAM CHANNEL for instant updates

Leave a Reply

Back to top button

Adblock Detected

Please turnoff your browser's Ad Blocker