Home Nigeria Gospel Music Yoruba Gospel Music Bi Mo Ba Fowo Kan Iseti Aso Re by Mrs D.A Fasoyin

Bi Mo Ba Fowo Kan Iseti Aso Re by Mrs D.A Fasoyin

0

Bi Mo Ba Fowo Kan Iseti Aso Re by Mrs D.A FasoyinMrs D.A Fasoyin, a well-known gospel artist, presents a beautiful song called ‘Bi Mo Ba Fowo Kan Iseti Aso Re’ This song is a special way to show love and respect to God, with lovely and catchy music.

It’s not just regular music; it’s like a bridge that connects people to something heavenly. Enjoy this amazing musical journey, get this unique song, and share the joy with your friends and family.”

DOWNLOAD MP3

Ara mi yo ya gaga – C.A.C Good Woman Choir, Ibadan. Led By Mrs D.A Fasoyin

Bi mo ba f’õwõkan isÄ™ti asõ rÄ™

Bi mo ba f’õwõkan isÄ™ti asõ rÄ™

Bi mo ba f’õwõkan isÄ™ti asõ rÄ™

Ara mi yio ya gaga, ara mi yio ya gaga

Igbagbõ la fi n rire gba lõwõ Baba

F’igbagbõ rõ m’Ä™ni to le gba õ, arakunrin

F’igbagbõ rõ m’Ä™ni to le gba õ, arabinrin

Gba t’iji aye ba yi lu o, sa gbÄ™kÄ™le

Ko gbogbo aniyan rÄ™ l’Oluwa, sa ti gbagbõ

Obinrin onisun Ä™jÄ™, to f’igbagbõ tõ Jesu wa nibÄ™ lo rire gba

Isun Ä™jÄ™ si duro lai t’ori p’o gbagbõ

Ara rÄ™ si ya gaga, ara rÄ™ si ya gaga

Bi mo ba f’õwõkan isÄ™ti asõ rÄ™

Bi mo ba f’õwõkan isÄ™ti asõ rÄ™

Bi mo ba f’õwõkan isÄ™ti asõ rÄ™

Ara mi yio ya gaga, ara mi yio ya gaga

Nipa Igbagbõ, AbÄ™li rubõ s’Õlõrun

Nipa igbagbõ, Enõku ba Õlõrun rin

Nipa igbagbõ, Abraham d’õrÄ™ Õlõrun

Nipa igbagbõ ni Noha d’olododo

O f’eti si õrõ Õlõrun

N’igba t’o kan õkõ igbala

Ikun omi de, õpõ si s’egbe

Kiki awõn to gbõ ti Noha nikan ni wõn la

Namani f’igbagbõ wÄ™ ninu omi, o d’asÄ™gun

Iwõ arakunrin (Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

Iwõ arabinrin (Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

B’ogun aye ba de (Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

B’ogun õta ba de (Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

B’o j’owo lo n fÄ™. (Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

B’o j’õmõ lo wu õ (Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

B’o jÄ™ ‘le lo fÄ™ kõ (Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

B’o j’owo lo fÄ™ se (Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

Iwõ ti ko ri jÄ™ (Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

Iwõ ti ko ri mu (Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

Agan ma ronu mõ(Sa ti f’igbagbõ rõ m’Oluwa)

Babalawo ko le se

Onisegun ko le se

Adahunse ko le s’õmõ f’igbagbõ rõ m’Oluwa

Ninu Bibeli, Ana f’igbagbõ rõ m’Oluwa

Agan r’õmõ gba t’ori p’o gbagbõ

Õlõrun f’Ana l’õmõ ara rÄ™ si ya gaga

Bi mo ba f’õwõkan isÄ™ti asõ rÄ™

Bi mo ba f’õwõkan isÄ™ti asõ rÄ™

Bi mo ba f’õwõkan isÄ™ti asõ rÄ™

Ara mi yio ya gaga, ara mi yio ya gaga

Join our whatsapp channel or telegram channel for instant updates

Leave A Reply

Please enter your comment!
Please enter your name here