
Tope Alabi Eruretoba Download
Download ERURETOBA by Tope Alabi features TY BELLO. ERURETOBA is off Tope Alabi’s 2019 album called THE SPIRIT OF LIGHT.
[ddownload id=”7724″]
Tope Alabi Eruretoba Lyrics
Erure to ba o
Obat to s’oro ti ina yö
Erure to ba o
Olorun to s’oro ti ina yö
Iwo to s’oro ti okun gbe
Iwo to s’oro okun-pupa gbe
Iwo to s’oro okun pupa la
Olorun to s’oro ti ina yo ()
Iwo to fi idin je odindi oba
Erure to ba o
Iwo to so estheri d’ayaba l’lojiji
Erure to ba o
O mu eru kuro laarin eru
O wa so eru d’oba ti gbogbo aye n wari fun
Erure to ba o
Eleda to s’oro ti ina jade o
O mu omi jade ninu apata
Ta lo da bi re o
O se oun t’enikan o le se
Olorun to tun aye awa naa se
Eni ta ti ro pe ko le pa go wa deni to kole ala ruru
Aya re too ja eniyan
Aya re ja mi
Ogo re yi po
Eru re to ba o
Erure to ba o