Home Music Sola Allyson — Ife A Dale Lyrics

Sola Allyson — Ife A Dale Lyrics

0
Sola Allyson Ife A Dale Lyrics
Sola Allyson Ife A Dale Lyrics
Advert Download Button

Sola Allyson Ife A Dale Lyrics

ife wa adale ife wa adale
Oooo
ife wa adale ife wa adale ire
ife wa adale ife wa adale
Oooo Bena ni
ife wa adale ife eyi adale ire

Ire latoke wa
Ibukun ti ki nsi lo
Ire ti kin gbo danu
Ife eyi adale o
Ire latoke wa
Ibukun ti ki nsi lo
Ire ti kin gbo danu
Ife eyi adale o

ife wa adale ife wa adale
Oooo
ife wa adale ife wa adale ire ( ao ni subu)
ife wa adale ife wa adale
Oooo Bena ni
ife wa adale ife eyi adale ire

Ire latoke wa
Ibukun ti ki nsi lo
Ire ti kin gbo danu
Ife eyi adale o
Ire latoke wa
Ibukun ti ki nsi lo
Ire ti kin gbo danu
Ife eyi adale o

ife wa adale ife wa adale (oju oni ti wa lailai)
Oooo
ife wa adale ife wa adale ire (ododun loa n rorogbo)
ife wa adale ife wa adale
Oooo Bena ni
ife wa adale ife eyi adale ire

Iranwo awa fun wa
Ojurere at alanu
iranwao awa fun wa
Agbara lowo eldumare adwa mu
idimu adiwa mu o

Ao ri ike ati ige lona wa
Ike ati ige amaba wa lo
Ike ati ige amaba wa lo

Ere akori ase po wa o
ere apo fun wa o

Imole atan fun o
imole nbawa lo lona gbogbo

Ire latoke wa
Ibukun ti ki nsi lo
Ire ti kin gbo danu
Ife eyi adale ire
Ire latoke wa
Ibukun ti ki nsi lo
Ire ti kin gbo danu
Ife eyi adale ire

ife wa adale ife wa adale (ife lagbokan le ao ni kuta laye)
Oooo
ife wa adale ife wa adale ire (idari atoke wa awa fun wa aoni sina)
ife wa adale ife wa adale
Oooo Bena ni
ife wa adale ife eyi adale ire (Awa teto ti sowa po ko sohun ti yo yawa)

ife wa adale ife wa adale
Oooo
ife wa adale ife wa adale ire
ife wa adale ife wa adale
Oooo Bena ni
ife wa adale ife eyi adale ire

DOWNLOAD Ife A D’ale AUDIO HERE


Join our WhatsApp GROUP or TELEGRAM CHANNEL for instant updates

Leave A Reply

Please enter your comment!
Please enter your name here