News

Oriki Olorun ni ijinle Yoruba

Oriki Olorun ni ijinle Yoruba
Oriki Olorun ni ijinle Yoruba

Oriki Olorun ni ijinle Yoruba

God eulogy

Alade ogo, olorun agbaye, oba awon oba, oba mimo, kabiyesi bi ire kosi, oba ti n je emi ni mase beru,

this i took from another forum, I love it

ogbamu gbamu oju orun o se gbamu
jesu ni ma sin,
I will worship Jesus
emi o sin popsie grandfather baba enikankan
I am not worshipping grandfather of nobody
okan loba, ijoye le kpe thirty
there is only one king while the asistance could be thirty
e ba je a say something repete,ka yin baba loke
let us say something big, to praise the father in heaven
olorun oba alagbara
God almighty
olorun oba, okiki imole
oba mi, oba aterere kari aye
my king that covers the whole earth
oba mi, oba arin ma to ika leyin
king that walk but has no back ache
gbirin leyin asododo
irawo owuro, oko mary
the morning star and mary’s husband
oba loni, oba lana, oba titi aye raye
the king today, yesterday and king forever
gbagba gba leyin asooto
ogbe inu wundia sola,
ogbe nu adelegbo o sogo,
ajanaku ti mi igbo kiji kiji
Tiger that shakes the jungle
oba mi okiki okaka, okaka okiki
ti n ki omo re leyin, kiki okiki
kiki imole, kiki ogo
full of light and glory
okiki mighty, okiki sweety
okiki honey,okiki ladun,
okiki loyin
oba mi oba adun bii oyin
my king, as sweet as honey
i am sorry sir
ale dun ju oyin lo
okiki, one-derful, 2-derful
3-derful,4-derful e.t.c(till 10-derful)
jesu mi edun ju, e dun kpa,
edun yo, e poju, e fine e preety, e handsome,
e, e, e, , in fact i am short of words
oba ti aki ki ki ta o le ki tan,
Re: The Yoruba Names Of God by vanitty: 1:56pm On Nov 22, 2009
Oba toto bi a ro (A King who is truly worthy)

Elewu oye (The one with is robed in royalty)

Aba nise ma pada lehin eni (The one who helps us till the end)

Abe ti lu kara bi ajere (“Ajere” in Yoruba is a type of mesh with wide holes used to make barbecued corn, fish etc. and this means God’s ear is always open to hear us all at the same time, His omnipresence might come to mind with this attribute)

Ada gba ma paro Oye, Agbalagba Oye (these 2 phrases mean the same thing, but said in different ways, It means an a King who’s royal forever, He never grows old, his kingship is eternal)

Adani ma gba gbe (The creator, who never forgets his creation)

A dani wa ye (The one creates us and places us on the planet earth)

Aduro tini lojo isoro (The one who stands by us in crisis)

Agbani lagbatan (The one who delivers completely)

Gbani, gbani tan sa ya (A deliverer that we can always run to for help)

Agbara nla to so Ile aiye ro (The power that upholds the world)

Ata ile aiye ro bi agogo (The ones who holds the world like a pendulum)

Oba to gbe aiye ro lo ri ofo (The one who suspends the earth on nothing. Halleluyah!!!)

Agbara to bori gbogbo agbara (The power that’s above all powers)

Agbo ma te ni o(The ancient One who never grows weak. Now we know that the strength of anyone wanes as they age, But Jehovah, never grows weak despite His age, Halleluyah!! This is past finding out)

Mountaintoppraise

Apa-nla-to sole-aye-ro; Adeda; Aseda; Ameda; Alagbada-ina; Alawotele-oorun; Gbengbeleku to ndara nibi to gbe wun; Alaani; Agbani; Afuuni; Atoni; Alewilese; Aleselewi; Gbani-gbani ti-aye-nsaaya; Ariro-ala; Arabaribiti; Aribirabata; Sonso ori abere to soro fun satani lati joko le; Opabi-da-sobi-dire; O joko kiribiti kale lajule orun, Oba mi to tele aye bi eni teni; O ta sanmo bi eni taso; Alapa kabikabi ti nkabi danu lori awon omo; Akobi ninu awon oku; Ajinde ati Iye; Kiki oro kan to so ile aye ro; Apata Ayeraiye; Apata aidigbolu-eni digbolu a wo womu-womu; Eleti lu kara bi ajere; Ape-je, Aipe-je; Baba fun alaini baba; Oko opo; Eru jeje leti okun pupa; Ekun oko Farao; Oke-tiiri ti-ko-le-wo; Oko mi; Olorun mi; Olugbala mi: Olurapada mi; Afuni teni keni ko le gba; Agbani te nikeni ko le de; Agbeni teda aye kan ko le ja kule;Olowo gbogboro ti nyomo re ninu ofin aye; Ara-ti-nsan-nigbo-ti-tigbo-tiju-pa-lolo-lo; Olowo-ori-mi; Oba awon oba; Olorun awon olorun, Afobaje ti a ko le ro loye; Oba to nfi oba je; Oba to nse ohun gbogbo lodu lodu to nje Olodumare; Ogbenu-wundia sola; Ogbenu adalebo sewa; O gbe nu omo eniyan fohun; Alfa ati Omega; Ibeere ati opin; Eni ibeere ati opin; Saju aye loti wa, aye wa, Baba mi wa sibe, Olorun mi ti yio ma wa nigba ti aye ko ni si mo;Emi ni ninu emi ni; Emi ni mase beru; Akara iye; odo to nsan fun aanu ti kii gbe; Ajidara; Ajisewa; Aiku Aidibaje; Alagbala iyanu; Alagbala a-de’u’re; Alagbala to ni kokoro to nsi to nti; Alade wura, Alade ogo; Alade ewa; Ewa to tinu ewa jade; olowo mimo; Oniwa mimo; Alade mimo; Mimo, mimo ninu ogo nla ti kii di baje, Oloruko egbaagbeje, And so on and so forth. Hope U are ok with these ones. He s got so[/b] many names i cant just remember at once

Oriki Edumare, Oriki Olodumare, Oriki Olorun, Oriki Oluwa, Oriki Odumare, Names of God in Yoruba Language, meanings in English. God’s Names and Meanings in YORUBA Language. Yoruba Praise Names of God, Great for Praise and Worship, Adoration, Reflection. ORUKO ati ORIKI Olorun. Oruko Olorun Ni Yoruba, Oriki Olorun, Oriki Oluwa. Oriki Oluwa Oba, Oriki Olorun, Oruko ati Oriki Olodumare Eledumare.
Names of God in Yoruba Language, Praise Names, God’s Names in Yoruba
Oluwa, (Lord)
Oluwa wa, (Our Lord)
Olorun, (God)
Olorun wa, (Our God)
Oluwa awon oluwa, (The Lord of Lords)
Olorun awon olorun,
Kabiyeesi, (The King)
Oba awon oba,( King of Kings)
Olodumare,( The Almighty)
Arugbo ojo,(Ancient of days)
Olorun agbalagba,( Ancient of days)
Adagba ma paaro oye,(Unchanging God)
Olorun ti o yipada, (Unchanging God)
Olorun kan lailai,( The only God)
Ikan lana,(Same yesterday)
Ikan loni, (Same today)
Ikan lola, (Same tomorrow)
Okan titi aye ainipekun, ( The same forever)
Oba ti mbe nibi gbogbo nigba gbogbo,( the ubiquitous God)
Metalokan,( The trinity)
Olorun Baba,(God the Father)
Olorun Omo,(God the son)
Olorun Emi Mimo, (God the Holy spirit)
Olorun Abrahamu, (God of Abraham)
Olorun Isaki, (God of Isaac)
Olorun Jakobu, (God of Jaco
Olorun owu,(The jealous God)
Olorun ti kii s’enia ti yio paro, (God that is not man that could change)
Alewilese, (He that can Speak and Act)
Aleselewi, (He that can Act and Speak)
Owibee sebee, (He that Speaks and Acts)
Awimayehun, ( He who Speaks and does not change His words)
Asoromaye, (He who prophesize and comes to past)
Onimajemu,( Covenant keeping God)
Olulana,(The wonderful way maker)
Olorun oro (Word), (The God of spoken work)
Oba to ti o gbe oro Re ga ju Oruko Re lo, (The God who exalts his word mor= that his name)
Olutoju wa, (Our Keeper)
Onibuore,(God whose barn is full of blessing)
Afunni ma s’iregun,(The God who blesses without asking for reward)
Adanimagbagbe, (The creator who never forgets the created)
Oyigiyigi, (Great and Mighty)
Alakoso orun at’aye, (The God of heaven)
Atogbojule,(Dependable God)
Alagbawi eda,(Defender)
Alagbada ina, (He that covers Himself with fire branded robe)
Alawotele oorun,(He whose underwear is Sun)
Asorodayo,(The god who give joy)
Oba t’o mu ‘banuje tan,(God who puts end to sorrow)
Ogbeja k’eru o ba onija,(God who fights for the defenseless)
Jagunjagun ode orun,(The great warrior of heaven)
Olowogbogboro,(God whose hand is long enough to reach at any length)
Olorun awon omo ogun,(The great warrior)
Aduro tini bi akoni eleru,(The faithful God)
Eru jeje l’eti okun pupa,( The Most powerful by the red sea)
Oba t’o mu iji dake roro,(God who commands the storm, peace be still)
Alaabo,(Our keeper)
Oluso,(Our guard)
Olupamo,(Our keeper)
Oludande,(Our deliverer)
Olugbala,(Our saviour)
Olutusile,(God of freedom)
Oludariji,(Our forgiver)
Oba t’o se’gun agbara ese, (God who delivers from hold of sin)
Oba t’o san gbogbo ‘gbese wa,(God who pays the price for our sins)
Olorun ajinde,(The resurrected Lord)
Olutunu,(Our comforter)
Olufe okan wa,(My lover)
Oba t’o yan wa fe,(God who has predestined us)
Olusegun,(The conqueror)
Ajasegun, (The conqueror
Gbanigbani ni’jo ogun le,(Our defense in time of war)
Ogbagba ti ngb’ara adugbo,( The Protector)
Oba t’o pin okun pupa n’iya,( God who parted the red sea)
Olorun t’o mu Jodani sa niwaju awon omo Re, (God who parted the river Jord=n)
Oba t’o bi odi Jeriko wo,(God who fell down the walls of Jericho)
Olorun t’o kolu Egipiti l’ara awon akobi re,(God who killed the first born=of the Egyptians)
Oba t’o ju gbogbo orisa lo,(The almighty God)
Olorun t’o tobi ju gbogbo aye lo,(Greater than all the earth)
Oba t’o da monamona fun ojo, The God who created lightening for the rain)
Aimope ani oje,
Oba to j’ewe at’egbo lo,
Oba to ni owa t’owa,(The God who commands)
Oba t’oni olo, t’olo, (The God who commands)
Oba t’oni k’owa, t’owa, (The God who commands)
Oba t’oni k’omasi, ti o si si mo,(The God who can close a door and no man=can open)
Oba t’ao ri, sugbon t’ari ise owo Re,(The unseen God but we can feel his=impact)
Olorun t’o n gbo adura, (God who hears prayers)
Oba t’o n dahun adura, (Prayer answering God)
Olorun t’ape t’o n je,(The God that you can call and he will answer)
Oba t’o n dahun adura pelu ina,(God that answered by fire)
Eleda,(Creator)
Akoda aye,(The first among all things)
Aseda orun,(He established the heavens)
Oba t’o fi’di aye s’ole s’ori omi,( He who established the earth on waters=
Oba t’o mo wa (The Potter),
Oba t’o mo wa ( He that knoweth us),
Oba t’o mo ohun gbogbo,(The all knowing God)
Olorun t’o le se ohun gbogbo,(God who can do all things)
Oba ti ohun gbogbo nbe n’ikawo Re,(God who has the whole world in his hand
Oba to joko soke orun to f’ile aye se itise Re,(He makes the heaven his se=t and the earth his foot stool)
Oba ti ntu won ka nibi ti won nti da’na iro,(He who causes confusion in th= camp of the enemy)
Atererekariaye,(He spreads out across the earth)
Eletigb’aroye,(The great hear that hears all over the world)
Alatilehin,(Our succor)
Alaanu,(Merciful God)
Oba ti aanu Re duro lailai,(God whose mercies endureth for ever)
Oba alade alafia,(The Prince of peace)
Oloore ofe,(The gracious god)
Olorun ife,(The God of Love)
Olorun ayo,(The God that gives Joy)
Olutunu,(Comforter)
Olubukun,(The blessed God)
Onise iyanu,(Miracle worker)
Onise ara,(Wonderful)
Onise nla,(Great God)
Mimo, Mimo, Mimo,(Holy! Holy! Holy)
Oba t’o ninu mimo,(Righteous God)
Oba alaya funfun,(Immaculate God)
Ologo meta, (The Trinity
Olotito,(The Truthful)
Olododo,(The Truthful)
Iye,(Resurrection)
Aduro gboingboin lehin asotito,(Defender of the Truthful)
Imole ninu okunkun aye,(The light in darkness)
Alagbara l’orun ati l’aye,(Mighty in heaven and on the earth)
Oba ti nyoni kuro ninu ofin aye,(God who rescues from the dungeon)
Atofarati,(Our defense)
Atogbokanle,(The trustworthy God)
Atofokante,(Our Confidant)
Adunbarin,(Worthy to walk with)
Adunbalo, (Worthy to follow)
Adunkepe,(God you can call on)
Apata ayeraye,(The rock of ages)
Atobiju,(The Almighty)
Atofarati bi oke,(Our support and defense)
Apata wa,(Our rock of Ages)
Odi wa,(Our shield)
Alabarin aye wa, (Our companion)
Olupese,(Our provider)
Olugbega,(The lifter of our head)
Oluranlowo,(Our help)
Ireti wa,(Our hope)
Olu aye,(God on earth)
Olu orun,(God in heaven)
Oba ti gbobo oba nt’owo Re gb’ase,(Kings from whom kings take directives)
Adakedajo, (He who Judges silently)
Adajo ma fi t’enikan se,(The just Judge)
Oba ti kii s’ojusaju,(The just God)
Oba t’enikan o le pe l’ejo,(The king that can not be judged)
Oba aseyiowu,(Unquestionable God)
Oba tii s’agan d’olomo,(The god who opens the womb of the barren)
Abiyamo ode orun,(The great mother of heaven)
Atorise,(God who can turn bad situation to good)
As’oloriburuku d’olorire,(God who can remove the inadequacies from ones li=e)
Arinu r’ode,(God who sees the visible an the invisible,)
Olumoranokan eda, (He who sees the intent of the heart of man)
Oludamoran (The Great adviser)
Baba wa,(Abba father)
Ore wa,(Our friend)
Ibi isadi wa,((Our refugee)
Aabo wa,(our protector)
Oluwosan,(the healer)
Asoku d’alaye,(He who brings the dead to life)
Olorun alaaye,(God of the living)
Oba ti n p’ojo iku da,(God who can change appointment with death)
Oba ti emi gbogbo enia wa l’owo Re,( He who has the keys to our existence)
Oba ti nti t’enikan o lesi,(He who shuts and no one can open)
Oba ti nsi t’enikan o leti,(He who opens and no one can close)
Awamaridi,(Unsearchable God)
Eleruniyin,
Abetilukara bi ajere,(God who is all ears)
Aiku,(Living God)
Aisa,(Faithful)
Oba ti ki sun, ti ki togbe (The king that neither sleeps nor slumbers)
Oba onise nla,(The great worker of good)
Onigbonwo wa, (Our sponsor)
Olorun pipe,(Perfect God)
Olorun rere,(Good God)
Akiri s’ore,(He who goes about doing good)
As’ore kiiri, ,(He who goes about doing good)
Gbongbo idile Jesse,(The root of the tribe of Jesse)
Oba t’o f’oro da ile aye,(He that created all things by his spoken word)
Oba to ti wa k’aye o towa,(He who was in existence before creation)
Oba ti o ma wa nigba t’aye o ni si mo,(He who will remain at the end of al= things)
Oloruko nla,(The great name)
Ologojulo,(The glorious God)
Emi ni ti nje Emi ni,(I am the I am)
Oba t’oni gbogbo ope,(He who deserves all praise)
Olorun t’oni gbogbo iyin, ,(He who deserves all honour)
Oba ti ko ni pin ogo Re pel’enikankan,(God that does not share his=glory with any man)
Oba t’o ti wa, t’o si wa, ti o si ma wa lailai, (The God that was, that is=and that will remain for ever)
Ibere ati opin, (The Alpha and omega)
OBA AKIKITAN, (Eternity will not be enough to praise and honour you, O Lord).
Oriki Olodumare Olorun:
Names of God in Yoruba Language, Praise Names, God’s Names in Yoruba (Oruko ati Oriki Olorun)

Praise and Worship in Yoruba
The Yoruba culture is very rich and supple in the names and attributes of God. This is a little compilation of some of these names.
We’ve also produced an audio CD extolling His majesty in the Yoruba language – “Oloruko Egbagbeje”, a thought provoking rendition that is just like a whisper, or simply call it “less than a dot” of who He is. Please click on the Items page on the menu bar to order a copy of this cd.
The book of Job recounts some of these attributes and acts and calls them a whisper -Job 26:14, a mere fringe of His force, His power -(emphasis mine)
————————————————— ———————
Oba toto bi a ro (A King who is truly worthy)
Elewu oye (The one with is robed in royalty)
Aba nise ma pada lehin eni (The one who helps us till the end)
Abe ti lu kara bi ajere (“Ajere” in Yoruba is a type of mesh with wide holes used to make barbecued corn, fish etc. and this means God’s ear is always open to hear us all at the same time, His omnipresence might come to mind with this attribute)
Ada gba ma paro Oye, Agbalagba Oye (these 2 phrases mean the same thing, but said in different ways, It means an a King who’s royal forever, He never grows old, his kingship is eternal)
Adani ma gba gbe (The creator, who never forgets his creation)
A dani wa ye (The one creates us and places us on the planet earth)
Aduro tini lojo isoro (The one who stands by us in crisis)
Agbani lagbatan (The one who delivers completely)
Gbani, gbani tan sa ya (A deliverer that we can always run to for help)
Agbara nla to so Ile aiye ro (The power that upholds the world)
Ata ile aiye ro bi agogo (The ones who holds the world like a pendulum)
Oba to gbe aiye ro lo ri ofo (The one who suspends the earth on nothing. Halleluyah!!!)
Agbara to bori gbogbo agbara (The power that’s above all powers)
Agbo ma te ni o(The ancient One who never grows weak. Now we know that the strength of anyone wanes as they age, But Jehovah, never grows weak despite His age, Halleluyah!! This is past finding out)
Baba mi arugbo ojo (My Father the ancient of Days)
Agboro dan alailara (the advocate of the defenseless)
Iwo lolugbeja omo orukan (The defender of the orphan)
Baba ati Olorun le je fun awon alaini baba (A father and a God to the fatherless)
Okiribiti, Aji po jo iku da (The one who can decide to cancel the day of death)
ihoho ni ipo-oku niwaju re(Death is naked, it can’t hide from Him)
Ibi iparun ko si ni iboju (Destruction has no hiding place from Him)
Ajoke aiye o(The one who rains on ALL the inhabitants of the earth), Aseke orun (The one who allows entrance into heaven, BUT on His terms)
Akan yan yan kan yin yin tin se ise Imole (The one who manages the various forms of light and heat-Sun, Moon, Stars etc)
Iwo la ko da aiye (Creator and owner of the world)
A se da orun (Creator of the heavenly beings)
Alaafin ode orun (Owner of the heavenlies)
Iwo la lade Ogo (The one with a Glorious Crown)
Alade wura (The one with the Golden Crown)
Oba alagbada imole (The one with the garment of light, His garment is not made of light, but it is light itself)
Alagbada Ina(The One with a garment of fire, His garment is not made of fire, but its fire itself, why, even the book of Hebrews tells us God is a consuming fire.
Adeola: I fear and honour a God so heavily loaded in all aspect!!!
Let’s move on…
Alagbala imole (His abode is light, We read in Revelations that the new Jerusalem is a city that has no light of its own, but the light is beaming from the glory of God).
Iwo la lagbala itura (The owner of the Home/Palace/Mansion of comfort)
Alagbala Ola to lla re nmi legbe legbe (The owner of the overflowing Opulent mansions of heaven.
(Let’s do all it takes to end up in one of them, Jehovah has stocked heaven with goodies for everyone who has accepted Jesus and loves Him dearly).
Alagbara laiye ati lorun (God has the supreme power on earth and in heaven)
Agbara re ki ba ti (His power always overcomes in any situation)
Alakoso orun (Supreme Director of heaven)
Alanu eda(Will always have mercy on his creation)
Alase laiye ato lorun (The lawgiver of the earth and heaven)
Alasepe ni o (Completer)
Alawo tele orun(The one who is so full of light into his very being)
A lewi lese, A lese lewi (This is the same phrase said in different ways it means – The one who says something and does what He says)
Alpha ati Omega (Means the same thing in English – Alpha and Omega)
Aanu ati ife ti ko lopin (He’s full of Mercy and Love that never ends)
Aanu re po bi iyanrin eti okun (His mercy is like the sand on the seashore)
Alaanu ni o ati Oloore (A God who has mercy and blesses)
Apase wa ni pa ase re la fi da ohun gbogbo (The one who has authority to give orders, and by His orders have all things been created)
Iwo lo pase fun owuro lati igba ojo re wa (He gave orders to the morning)
O si mu ila orun mo ipo re (He shows the dawn its place. “Ila Orun” is the rising of the sun, “Iwo orun” is the going down of the sun)
Apata aiyeraiye o!(O Rock of Ages!!!)
Ibi isadi olododo,(The refuge of the righteous)
Apata ti ko se fo ri so, Apata idigbolu (He’s like a rock, and can’t be defeated)
Eni aiyeraiye (The Eternal One)
Aribirabata, aribirabata (A humongous God, A Mighty, Great God)
Araba ti ki ku (An Oak that never dies)
Olorun ti ko seun ti (A God who makes impossibilities possible)
Arugbo ojo gbogbo (The ancient one who spans the past, present and the future)
Olorun kan lailai taiye atorun mbo (The eternal God whom the earth and heavens worship)
A se yio wu ni o,(He does as He pleases)
Baba mi ta o le pe lejo (My father that can’t be summoned for questioning)
O du abo-ogongo loye (He gave no wisdom to the Ostrich
(Ostriches don’t dig holes to lay their eggs like most animals would, they lay it on the plain ground).
Ofi agbara fun esin (He gave the horse its strength)
Nipa ase re ni idi nfi fo lo soke ki o le lo te ite re si oke giga (By the order of the Almighty, the eagle soars to heights to build its nest)
Oba to da oni nla la laini iberu, ninu gbogbo ohun to da sori ile aiye (He created the crocodile to be fearless amongst all His creatures)
Oni dajo ododo,(The One who makes righteous judgements)
Asiwaju eda (The leader of creation)
Asiwaju ohun gbogbo(The leader of all things)
Asoro ma ta se (The one whose words never fails)
Awimayehun (The ones who will not go back on His words)
Iwo la so ro ma ye(His word will always stand and not fail)
Awa ma ri di (A very very mysterious God)
Ijinle Ife (Original Lover, His love is original, its real)
Jehovah Rapha (The healer)#
Awogba arun ma gbe je(The physician who demands heals so many diseases for free)
Awuwo ma se gbe (the ones who can’t be overthrown)
Oba ti nwo. sugbon aiye eni san (The healer of our weaknesses)
Asi ma so egun gbigbe eni da(The one who revives our dry bones/lifeless areas of our lives)
Commander ni o ninu awon orun(The Commander of the heavens)
Ekun oko Pharaoh (The Powerful One who controls every Pharoah of our lifes – Pharoah in christianity means anything that will not let allow or limits our ability to do the will of God in Success/health/Marriage etc)
Eleburu ike O! (O, He’s so full of care – he overflows with cares for us)
Olorun Erujeje (A God to be feared)
Eledumare (God)
Eleyinju Imole (The one with the eyeballs of Holiness/Light)
Eleeda ohun gbogbo(creator of all things)
Eleeda orun ati aiye (Creator of the earth and the heaven)
Eleru ni yin(God is Fearful in praise)
Eleti gbohun gba ro ye (He’s attentive to whatever we have to say)
Elewu oye (The ones who wears a garment of Royalty)
Eni iyanu(A Miracle working God)
Eni ko o mo (Anyone that challenges Him delibrately Him, does not really know who they are up against)
Eni mo o ko(Those who know Him, don’t dare challenge Him, The bible says the demons know God and they tremble)
Enita ki ki ki ta o le ki tan(You can never exhaust all his attributes, remember Job 26:14)
Eni ti nrin lori iye apa afefe (He moves on the wings of the wind)
To fi awosanma se keke re (He makes the clouds His chariots)
Iwo lo fi aiye sole lori ipile re ti ko le sipo pada lailai (He has established the foundation of the earth that can’t be moved forever)
Eri Olola (Evidence of the wealthy)
Eleri Ikehin (The supplier of the evidence at the end/close of the ages- judgemental evidences)
Iwo loba to mo Iwon ipinle aiye,(The one who measured the foundations of the earth)
O da Okun ati Iyangbe ile, oorun osuupa ati awon irawo, (He created the ocean and the dry ground, The sun, moon and the stars)
Oda osuupa fun akoko(He created the moon for certain times and seasons)
Oorun mo akoko iwo re(The sun knows when it’s time to go down)
O wa fi omi bo ipile aiye mole bi aso (You covered the foundation of the earth with water as with a garment.)
Oba mi eyin le kan okuta igun ipile aiye (My King, you are the one who sets the cornerstone of the earth in place)
Efi ilekun se omi okun mo nigbati o ya jade bi enipe o ti inu tu jade wa (You marked the boundaries for the waters when you created them)
Oba to fi awosanma se aso okun (You made clouds as garments for the ocean)
O si fi okunkun sisu se oja igbanu re (The depths of the ocean is dark, because you made it so.)
Oba ti nki sojusaju awon omo-alade beni ki nka oloro si ju talaka lo , nitoripe ise owo re ni gbogbo won je (A king that doesn’t impress the rich and famous and He does not favor the rich over the poor, because they are all the work of His hands)
Nipa ti Olodumare awa ko le wa di re (The ways of God is past finding out)
O rekoja ni ipa(He is execellent in might)
O ki iba idajo ati opolopo otito (He is a righteous Judge)
Eniti ofo ilekun ide (He that broke the gates of brass)
O si ke opa-idabu irin si agbedemeji (..and cuts the bars of iron in sunder)
Eru re saa lo mba mi erujeje (I fear you my God)
Eru jeje leti okun pupa(God was feared at the banks of the red sea because of His acts)
Ogo ni fun oruko mimo re ni oruko nla Jesu. Amin (I glorify your Holy name in Jesus name. Amen.)

The Names of God in Yoruba Language – Oruko ati Oriki Olorun

Here’s a list of Yoruba Praise Names for God aka Oriki as well as their meanings in English.
A dani wa ye – The one creates us and places us on the planet earth
A se da orun – Creator of the heavenly beings
A se yio wu ni o – He does as He pleases
Aabo wa – Our protector
Aanu ati ife ti ko lopin – He’s full of mercy and love that never ends
Aanu re po bi iyanrin eti okun – His mercy is like the sand on the seashore
Aba nise ma pada lehin eni – The one who helps us till the end
Abe ti lu kara bi ajere – God’s ear is always open to hear us all at the same time
Abetilukara bi ajere – God who is all ears
Abiyamo ode orun – The great mother of heaven
Ada gba ma paro oye – The King who is royal forever
Adagba ma paaro oye – Unchanging God
Adajo ma fi t’enikan se – The just Judge
Adakedajo – He who Judges silently
Adani ma gba gbe – The creator, who never forgets his creation
Adunbalo – Worthy to follow
Adunbarin – Worthy to walk with
Adunkepe – God you can call on
Aduro gboingboin lehin asotito – Defender of the Truthful
Aduro tini bi akoni eleru – The faithful God
Aduro tini lojo isoro – The one who stands by us in crisis
Afunni ma s’iregun – The God who blesses without asking for reward
Agbalagba oye -, He never grows old, His kingship is eternal
Agbani lagbatan – The one who delivers completely
Agbara nla to so Ile aiye ro – The power that upholds the world
Agbara re ki ba ti – His power always overcomes in any situation
Agbara to bori gbogbo agbara – The power that’s above all powers
Agbo ma te ni o – The ancient One who never grows weak
Agboro dan alailara – The advocate of the defenseless
Aiku – Living God
Aisa – Faithful
Ajasegun – The Conqueror
Ajoke aiye o – The one who rains on all the inhabitants of the earth
Akan yan yan kan yin yin tin se ise Imole – The one who manages the various forms of light/heat-Sun, Moon, Stars etc
Akiri s’ore – He who goes about doing good
Akoda aye – The first among all things
Alaabo – Our keeper
Alaafin ode orun – Owner of the heavenlies
Alaanu – Merciful God
Alaanu ni o ati Oloore – A God who has mercy and blesses
Alabarin aye wa – Our companion
Alade wura – The one with the Golden Crown
Alagbada Ina – The One with a garment of fire
Alagbala imole – His abode is light
Alagbala Ola to lla re nmi legbe legbe – The owner of the overflowing opulent mansions of heaven.
Alagbara l’orun ati l’aye – Mighty in heaven and on the earth
Alagbara laiye ati lorun – God has the supreme power on earth and in heaven
Alagbawi eda – Defender
Alakoso orun – Supreme Director of heaven
Alakoso orun at’aye – The God of heaven
Alanu eda – Will always have mercy on his creation
Alase laiye ato lorun – The lawgiver of the earth and heaven
Alasepe ni o – Completer
Alatilehin – Our succor
Alawo tele orun – The one who is so full of light
Alawotele oorun – He whose underwear is Sun
Aleselewi – He that can Act and Speak
Alewilese – He that can Speak and Act
Alpha ati Omega – Alpha and Omega
Apase wa ni pa ase re la fi da ohun gbogbo – The one who has authority to give orders, and by His orders have all things been created
Apata aiyeraiye – Rock of Ages
Apata ayeraye – The Rock of ages
Apata ti ko se fo ri so, Apata idigbolu – He’s like a rock, and can’t be defeated
Apata wa – Our Rock of Ages
Araba ti ki ku – An Oak that never dies
Aribirabata – A Great God
Arinu r’ode – God who sees the visible and the invisible
Arugbo ojo – Ancient of days
Arugbo ojo gbogbo – The ancient one who spans the past, present and the future
As’oloriburuku d’olorire – God who can remove the inadequacies from ones life
As’ore kiiri – He who goes about doing good
Aseda orun – He established the heavens
Aseke orun – The one who allows entrance into heaven, but on His terms
Asi ma so egun gbigbe eni da – The one who revives our dry bones/lifeless areas of our lives
Asiwaju eda – The leader of creation
Asiwaju ohun gbogbo – The leader of all things
Asoku d’alaye – He who brings the dead to life
Asoro ma ta se – The one whose words never fails
Asorodayo – He who gives joy
Asoromaye – He who prophesies and it comes to past
Ata ile aiye ro bi agogo – The One who holds the world like a pendulum
Atererekariaye – He spreads out across the earth
Atobiju – The Almighty
Atofarati – Our defense
Atofarati bi oke – Our support and defense
Atofokante – Our Confidant
Atogbojule – Dependable God
Atogbokanle – The trustworthy God
Atorise – God who can turn a bad situation to good
Awa ma ri di – Mysterious God
Awamaridi – Unsearchable God
Awimayehun – He who speaks and does not change His words
Awogba arun ma gbe je – The physician who heals for free
Awuwo ma se gbe – The one who can’t be overthrown
Baba ati Olorun le je fun awon alaini baba – A father and a God to the fatherless
Baba mi arugbo ojo – My Father the ancient of Days
Baba mi ta o le pe lejo – My father that can’t be summoned for questioning
Baba wa – Our father
Commander ni o ninu awon orun – The Commander of the heavens
Efi ilekun se omi okun mo nigbati o ya jade bi enipe o ti inu tu jade wa – You marked the boundaries for the waters when you created them
Ekun oko Pharaoh – The powerful One who destroys every Pharaoh (stumbling blocks) in our lives
Eleburu ike – God who’s care for us overflows
Eleda – Creator
Eledumare – God
Eleeda ohun gbogbo – Creator of all things
Eleeda orun ati aiye – Creator of the earth and the heaven
Eleri Ikehin – The supplier of the evidence at judgment
Eleru ni yin – God is fearful in praise
Eleti gbohun gba ro ye – He’s attentive to whatever we have to say
Eletigb’aroye – The great ear that hears all over the world
Elewu oye – The One robed in royalty
Eleyinju Imole – The One with Holy eyes
Emi ni ti nje Emi ni – I am the I am
Eni aiyeraiye – The Eternal One
Eni iyanu – Miracle working God
Eni ko o mo – Those who challenge Him, do not know Who they are up against
Eni mo o ko – Those who know Him, do not dare challenge Him
Eni ti nrin lori iye apa afefe – He moves on the wings of the wind
Enita ki ki ki ta o le ki tan – You can never exhaust all His attributes
Eniti ofo ilekun ide – He that broke the gates of brass
Eri Olola – Evidence of the wealthy
Eru jeje l’eti okun pupa – The Most powerful by the red sea
Eru re saa lo mba mi erujeje – I fear you my God
Gbani, gbani tan sa ya – A deliverer that we can always run to for help
Gbanigbani ni’jo ogun le – Our defense in time of war
Gbongbo idile Jesse – The root of the tribe of Jesse
Ibere ati opin – The Alpha and omega
Ibi iparun ko si ni iboju – Destruction has no hiding place from Him
Ibi isadi olododo – The refuge of the righteous
Ibi isadi wa – – Our refuge
ihoho ni ipo-oku niwaju re – Death is naked, it can’t hide from Him
Ijinle Ife – Original Lover
Ikan lana – Same yesterday
Ikan lola – Same tomorrow
Ikan loni – Same today
Imole ninu okunkun aye – The light in darkness
Ireti wa – Our Hope
Iwo la ko da aiye – Creator and owner of the world
Iwo la lade Ogo – The One with a Glorious Crown
Iwo la lagbala itura – The owner of the palace of comfort
Iwo la so ro ma ye – His word will always stand and not fail
Iwo lo fi aiye sole lori ipile re ti ko le sipo pada lailai – He who has established the foundation of the earth that can’t be moved forever
Iwo lo pase fun owuro lati igba ojo re wa – He gave orders to the morning
Iwo loba to mo Iwon ipinle aiye – The one who measured the foundations of the earth
Iwo lolugbeja omo orukan – The defender of the orphan
Iye – Resurrection
Jagunjagun ode orun – The great warrior of heaven
Jehovah Rapha – The Healer
Kabiyeesi – The King
Metalokan – The Trinity
Mimo, Mimo, Mimo – Holy! Holy! Holy
Nipa ase re ni idi nfi fo lo soke ki o le lo te ite re si oke giga – By the order of the Almighty, the eagle soars to heights to build its nest
Nipa ti Olodumare awa ko le wa di re – The ways of God is past finding out
O da Okun ati Iyangbe ile, oorun osuupa ati awon irawo – Creator of the sea, land, sun, moon and stars
O ki iba idajo ati opolopo otito – Righteous Judge
O rekoja ni ipa – Excellent in might
O si ke opa-idabu irin si agbedemeji – He cut the bars of iron in sunder
O si mu ila orun mo ipo re – He shows the dawn its place.
O wa fi omi bo ipile aiye mole bi aso – He covered the foundation of the earth with water as with a garment.
Oba Akikitan – Eternity will not be enough to praise and honour you, O Lord.
Oba alade alafia – The Prince of peace
Oba alagbada imole – The one with the garment of light
Oba alaya funfun – Immaculate God
Oba aseyiowu – Unquestionable God
Oba awon oba – King of Kings
Oba lana, Oba loni, Oba titi ayeraye – God of yesterday, God of today, God forver
Oba mi eyin le kan okuta igun ipile aiye – My King, who sets the cornerstone of the earth in place
Oba onise nla – The great worker of good
Oba t’ao ri, sugbon t’ari ise owo Re – The God whom we can not see but whose handwork we see
Oba t’ao ri, sugbon t’ari ise owo Re – The unseen God but we can feel his=impact
Oba t’enikan o le pe l’ejo – The king that can not be judged
Oba t’o bi odi Jeriko wo – God who fell down the walls of Jericho
Oba t’o da monamona fun ojo – The God who created lightning for the rain
Oba t’o f’oro da ile aye – He that created all things by his spoken word
Oba t’o fi’di aye s’ole s’ori omi – He who established the earth on waters
Oba t’o ju gbogbo orisa lo – The almighty God
Oba t’o mo ohun gbogbo – The all knowing God
Oba t’o mo wa – He that knoweth us
Oba t’o mo wa – The Potter
Oba t’o mu ‘banuje tan – God who puts an end to sorrow
Oba t’o mu iji dake roro – God who commands the storm, peace be still
Oba t’o n dahun adura – Prayer answering God
Oba t’o n dahun adura pelu ina – God that answered by fire
Oba t’o ninu mimo – Righteous God
Oba t’o pin okun pupa n’iya – God who parted the red sea
Oba t’o san gbogbo ‘gbese wa – God who pays the price for our sins
Oba t’o se’gun agbara ese – God who delivers from the grip of sin
Oba t’o ti wa, t’o si wa, ti o si ma wa lailai – The God that was, is and forever shall be
Oba t’o yan wa fe – God who has predestined us
Oba t’oni gbogbo ope – He who deserves all praise
Oba t’oni k’omasi, ti o si si mo – The God who can close a door and no man can open it
Oba t’oni k’owa, t’owa – The God who commands
Oba t’oni olo, t’olo – The God who commands
Oba ti aanu Re duro lailai – God whose mercies endureth for ever
Oba ti emi gbogbo enia wa l’owo Re – He who has the keys to our existence
Oba ti gbobo oba nt’owo Re gb’ase – Kings from whom kings take directives
Oba ti ki sun, ti ki togbe – The king that neither sleeps nor slumbers
Oba ti kii s’ojusaju – The just God
Oba ti ko ni pin ogo Re pel’enikankan – God that does not share his glory with any man
Oba ti mbe nibi gbogbo nigba gbogbo – The ubiquitous God
Oba ti n p’ojo iku da – God who can change one’s appointment with death
Oba ti nki soju saju awon omo-alade beni ki nka oloro si ju talaka lo , nitoripe ise owo re ni gbogbo won je – A King that doesn’t impress the rich/famous, nor favor the rich over the poor, because they are all the work of His hands
Oba ti nsi t’enikan o leti – He who opens and no one can close
Oba ti nti t’enikan o lesi – He who shuts and no one can open
Oba ti ntu won ka nibi ti won nti da’na iro – He who causes confusion in the camp of the enemy
Oba ti nwo. sugbon aiye eni san – The healer of our weaknesses
Oba ti nyoni kuro ninu ofin aye – God who rescues from the dungeon
Oba ti o ma wa nigba t’aye o ni si mo – He who will remain at the end of all things
Oba ti ohun gbogbo nbe n’ikawo Re – God who has the whole world in His hands
Oba ti s’agan d’olomo – The God who opens the womb of the barren
Oba titi ayeraye – God forever
Oba to fi awosanma se aso okun – You made clouds as garments for the ocean
Oba to gbe aiye ro lo ri ofo – The one who suspends the earth on nothing. Halleluyah!!!
Oba to joko soke orun to f’ile aye se itise Re – He makes the heaven His seat and the earth His footstool
Oba to ni owa t’owa – The God who commands
Oba to ti o gbe oro Re ga ju Oruko Re lo – The God who exalts His word more that His name
Oba to ti wa k’aye o towa – He who was in existence before creation
Oba toto bi a ro – A King who is truly worthy
Oda osuupa fun akoko(He created the moon for certain times and seasons
Odi wa – Our shield
Ofi agbara fun esin – He gave the horse its strength
Ogbagba ti ngb’ara adugbo – The Protector
Ogbeja k’eru o ba onija – God who fights for the defenseless
Ogo ni fun oruko mimo re ni oruko nla Jesu. Amin – I glorify your Holy name in Jesus name. Amen.
Okan titi aye ainipekun – The same forever
Okiribiti, Aji po jo iku da – The one who can decide to cancel the day of death
Olododo – The Truthful
Olodumare – The Almighty
Ologo meta – The Trinity
Ologojulo – The Glorious God
Oloore ofe – The Gracious God
Oloruko nla – The Great name
Olorun – God
Olorun Abrahamu – God of Abraham
Olorun agbalagba – Ancient of days
Olorun ajinde – The resurrected Lord
Olorun alaaye – God of the living
Olorun awon omo ogun – The great warrior
Olorun ayo – The God that gives Joy
Olorun Baba – God the Father
Olorun Emi Mimo – God the Holy spirit
Olorun Erujeje – A God to be feared
Olorun ife – The God of Love
Olorun Isaki – God of Isaac
Olorun Jakobu – God of Jacob
Olorun kan lailai – The only God
Olorun kan lailai taiye atorun mbo – The eternal God whom the earth and heavens worship
Olorun Omo – God the son
Olorun oro – Word – The God of spoken work
Olorun owu – The jealous God
Olorun pipe – Perfect God
Olorun rere – Good God
Olorun t’ape t’o n je – The God that you can call and He will answer
Olorun t’o kolu Egipiti l’ara awon akobi re – God who killed the first born of the Egyptians
Olorun t’o le se ohun gbogbo – God who can do all things
Olorun t’o mu Jodani sa niwaju awon omo Re – God who parted the River Jordan for His children
Olorun t’o n gbo adura – God who hears prayers
Olorun t’o tobi ju gbogbo aye lo – God who is greater than all the earth
Olorun t’oni gbogbo iyin – He who deserves all honour
Olorun ti kii s’enia ti yio paro – God that is not man that can change i.e. reliable God
Olorun ti o yipada – Unchanging God
Olorun wa – Our God
Olotito – The Truthful
Olowogbogboro – God whose hand is long enough to reach anywhere
Olu aye – God on earth
Olu orun – God in heaven
Olubukun – The Blessed God
Oludamoran – The Great adviser
Oludande – Our deliverer
Oludariji – Our forgiver
Olufe okan wa – Lover of our soul
Olugbala – Our Saviour
Olugbega – The lifter of our head
Olulana – The wonderful way maker
Olumoranokan eda – He who sees the intent of the heart of man
Olupamo – Our Keeper
Olupese – Our Provider
Oluranlowo – Our help
Olusegun – The Conqueror
Oluso – Our guard
Olutoju wa – Our Keeper
Olutunu – Comforter
Olutusile – God of freedom
Oluwa – Lord
Oluwa awon oluwa – The Lord of Lords
Oluwa wa – Our Lord
Oluwosan – The healer
Onibuore – God whose barn is full of blessing
Onigbonwo wa – Our Sponsor
Onimajemu – Covenant keeping God
Onise ara – Wonderful God
Onise iyanu – Miracle worker
Onise nla – Great God
Ore wa – Our friend
Owibee sebee – He that Speaks and Acts
Oyigiyigi – Great and Mighty
IYANU TI SHELE


Join our WhatsApp Group 1 | Group 2 | Group 3 | Group 4 | Group 5 or Telegram Channel for instant updates

Leave a Reply

Back to top button

Adblock Detected

Please turnoff your browser's Ad Blocker