
- Oluwa, (Lord)
- Olorun, (God) Olorun Wa, (Our God)
- Oluwa Wa, (Our Lord)
- Olorun Baba, (God the Father)
- Olorun Omo, (God the son)
- Olorun Abrahamu, (God of Abraham)
- Olorun Isaki, (God of Isaac)
- Oba awon oba,( King of kings)
- Olorun Emi Mimo, (God the Holy spirit)
- Oluwa awon oluwa, (The Lord of lords)
- Olorun awon olorun, (The God of gods)
- Kabiyeesi, (The King)
- Olodumare, (The Almighty)
- Arugbo ojo,(Ancient of days)
- Olorun agbalagba, (Ancient of days)
- Ikan lana,(Same yesterday)
- Adagba ma paaro oye, (Unchanging God)
- Olorun ti o yipada, (Unchanging God)
- Olorun kan lailai, (The only God)
- Ikan loni, (Same today)
- Okan titi aye ainipekun, (The same forever)
- Oba ti mbe nibi gbogbo nigba gbogbo,( the ubiquitous God)
- Olorun Jakobu, (God of Jacob)
- Ikan lola, (Same tomorrow)
- Olorun owu,(The jealous God)
- Olorun ti kii s’enia ti yio paro, (God that is not man that could change)
- Alewilese, (He that can Speak and Act)
- Aleselewi, (He that can Act and Speak)
- Owibee sebee, (He that Speaks and Acts)
- Awimayehun, ( He who Speaks and does not change His words)
- Asoromaye, (He who prophesize and comes to past)
- Onimajemu,( Covenant keeping God)
- Olulana,(The wonderful way maker)
- Olorun oro (Word), (The God of spoken word)
- Oba to ti o gbe oro Re ga ju Oruko Re lo, (The God who exalts his word more that his name)
- Olutoju wa, (Our Keeper)
- Onibuore,(God whose barn is full of blessing)
- Afunni ma s’iregun,(The God who blesses without asking for reward)
- Adanimagbagbe, (The creator who never forgets the created)
- Oyigiyigi, (Great and Mighty)
- Alakoso orun at’aye, (The God of Heaven)
- Atogbojule,(Dependable God)
- Alagbawi eda,(Defender)
- Alagbada ina, (He that covers Himself with fire branded robe)
- Alawotele oorun,(He whose underwear is Sun)
- Asorodayo,(The God who gives joy)
- Oba t’o mu ‘banuje tan,(God who puts end to sorrow)
- Ogbeja k’eru o ba onija,(God who fights for the defenseless)
- Jagunjagun ode orun,(The great warrior of heaven)
- Olowogbogboro,(God whose hand is long enough to reach at any length)
- Olorun awon omo ogun,(The great warrior)
- Aduro tini bi akoni eleru,(The faithful God)
- Eru jeje l’eti okun pupa,( The Most powerful by the red sea)
- Oba t’o mu iji dake roro,(God who commands the storm, peace be still)
- Alaabo,(Our keeper)
- Oluso,(Our guard)
- Olupamo,(Our keeper)
- Oludande,(Our deliverer)
- Olugbala,(Our saviour)
- Olutusile,(God of freedom)
- Oludariji,(Our forgiver)
- Oba t’o se’gun agbara ese, (God who delivers from hold of sin)
- Oba t’o san gbogbo ‘gbese wa,(God who pays the price for our sins)
- Olorun ajinde,(The resurrected Lord)
- Olutunu,(Our comforter)
- Olufe okan wa,(My lover)
- Oba t’o yan wa fe,(God who has predestined us)
- Olusegun,(The conqueror)
- Ajasegun, (The conqueror)
- Gbanigbani ni’jo ogun le,(Our defense in time of war)
- Ogbagba ti ngb’ara adugbo,( The Protector)
- Oba t’o pin okun pupa n’iya,( God who parted the red sea)
- Olorun t’o mu Jodani sa niwaju awon omo Re, (God who parted the river Jordan)
- Oba t’o bi odi Jeriko wo,(God who fell down the walls of Jericho)
- Olorun t’o kolu Egipiti l’ara awon akobi re,(God who killed the first born of the Egyptians)
- Oba t’o ju gbogbo orisa lo,(The Almighty God)
- Olorun t’o tobi ju gbogbo aye lo,(Greater than all the earth)
- Oba t’o da monamona fun ojo, (The God who created lightening for the rain)
- Aimope ani oje,(He who is not called but answers
) - Oba to j’ewe at’egbo lo, (kings mightier than herbs and roots)
- Oba to ni owa t’owa,(The God who commands)
- Oba t’oni olo, t’olo, (The God who commands)
- Oba t’oni k’owa, t’owa, (The God who commands)
- Oba t’oni k’omasi, ti o si si mo,(The God who can close a door and no man can open)
- Oba t’ao ri, sugbon t’ari ise owo Re,(The unseen God but we can feel his impact)
- Olorun t’o n gbo adura, (God who hears prayers)
- Oba t’o n dahun adura, (Prayer answering God)
- Olorun t’ape t’o n je,(The God that you can call and he will answer)
- Oba t’o n dahun adura pelu ina,(God that answered by fire)
- Eleda,(Creator)
- Akoda aye,(The first among all things)
- Aseda orun,(He established the heavens)
- Oba t’o fi’di aye s’ole s’ori omi,( He who established the earth on waters)
- Oba t’o mo wa (The Potter),
- Oba t’o mo wa ( He that knoweth us),
- Oba t’o mo ohun gbogbo,(The all knowing God)
- Olorun t’o le se ohun gbogbo,(God who can do all things)
- Oba ti ohun gbogbo nbe n’ikawo Re,(God who has the whole world in his hands)
- Oba to joko soke orun to f’ile aye se itise Re,(He makes the heaven his seat and the earth his foot stool)
- Oba ti ntu won ka nibi ti won nti da’na iro,(He who causes confusion in the camp of the enemy)
- Atererekariaye,(He spreads out across the earth)
- Eletigb’aroye,(The great hear that hears all over the world)
- Alatilehin,(Our succor)
- Alaanu,(Merciful God)
- Oba ti aanu Re duro lailai,(God whose mercies endureth for ever)
- Oba alade alafia,(The Prince of peace)
- Oloore ofe,(The gracious god)
- Olorun ife,(The God of Love)
- Olorun ayo,(The God that gives Joy)
- Olutunu,(Comforter)
- Olubukun,(The blessed God)
- Onise iyanu,(Miracle worker)
- Onise ara,(Wonderful)
- Onise nla,(Great God)
- Mimo, Mimo, Mimo,(Holy! Holy! Holy)
- Oba t’o ninu mimo,(Righteous God)
- Oba alaya funfun,(Immaculate God)
- Ologo meta, (The Trinity)
- Olotito,(The Truthful)
- Olododo,(The Truthful)
- Iye,(Resurrection)
- Aduro gboingboin lehin asotito,(Defender of the Truthful)
- Imole ninu okunkun aye,(The light in darkness)
- Alagbara l’orun ati l’aye,(Mighty in heaven and on the earth)
- Oba ti nyoni kuro ninu ofin aye,(God who rescues from the dungeon)
- Atofarati,(Our defense)
- Atogbokanle,(The trustworthy God)
- Atofokante,(Our Confidant)
- Adunbarin,(Worthy to walk with)
- Adunbalo, (Worthy to follow)
- Adunkepe,(God you can call on)
- Apata ayeraye,(The rock of ages)
- Atobiju,(The Almighty)
- Atofarati bi oke,(Our support and defense)
- Apata wa,(Our rock of Ages)
- Odi wa,(Our shield)
- Alabarin aye wa, (Our companion)
- Olupese,(Our provider)
- Olugbega,(The lifter of our head)
- Oluranlowo,(Our help)
- Ireti wa,(Our hope)
- Olu aye,(God on earth)
- Olu orun,(God in heaven)
- Oba ti gbobo oba nt’owo Re gb’ase,(Kings from whom kings take directives)
- Adakedajo, (He who Judges silently)
- Adajo ma fi t’enikan se,(The just Judge)
- Oba ti kii s’ojusaju,(The just God)
- Oba t’enikan o le pe l’ejo,(The king that can not be judged)
- Oba aseyiowu,(Unquestionable God)
- Oba tii s’agan d’olomo,(The God who opens the womb of the barren)
- Abiyamo ode orun,(The great mother of heaven)
- Atorise,(God who can turn bad situation to good)
- As’oloriburuku d’olorire,(God who can remove the inadequacies from ones life)
- Arinu r’ode,(God who sees the visible and the invisible,)
- Olumoranokan eda, (He who sees the intent of the heart of man)
- Oludamoran (The Great adviser)
- Baba wa,(Abba father)
- Ore wa,(Our friend)
- Ibi isadi wa,(Our refugee)
- Aabo wa,(our protector)
- Oluwosan,(the healer)
- Asoku d’alaye,(He who brings the dead to life)
- Olorun alaaye,(God of the living)
- Oba ti n p’ojo iku da,(God who can change appointment with death)
- Oba ti emi gbogbo enia wa l’owo Re,( He who has the keys to our existence)
- Oba ti nti t’enikan o lesi,(He who shuts and no one can open)
- Oba ti nsi t’enikan o leti,(He who opens and no one can close)
- Awamaridi,(Unsearchable God)
- Eleruniyin,
- Abetilukara bi ajere,(God who is all ears)
- Aiku,(Living God)
- Aisa,(Faithful)
- Oba ti ki sun, ti ki togbe (The king that neither sleeps nor slumbers)
- Oba onise nla,(The great worker of good)
- Onigbonwo wa, (Our sponsor)
- Olorun pipe,(Perfect God)
- Olorun rere,(Good God)
- Akiri s’ore,(He who goes about doing good)
- As’ore kiiri, ,(He who goes about doing good)
- Gbongbo idile Jesse,(The root of the tribe of Jesse)
- Oba t’o f’oro da ile aye,(He that created all things by his spoken word)
- Oba to ti wa k’aye o towa,(He who was in existence before creation)
- Oba ti o ma wa nigba t’aye o ni si mo,(He who will remain at the end of all things)
- Oloruko nla,(The great name)
- Ologojulo,(The glorious God)
- Emi ni ti nje Emi ni,(I am the I am)
- Oba t’oni gbogbo ope,(He who deserves all praise)
- Olorun t’oni gbogbo iyin, ,(He who deserves all honour)
- Oba ti ko ni pin ogo Re pel’enikankan,(God that does not share his glory with any man)
- Oba t’o ti wa, t’o si wa, ti o si ma wa lailai, (The God that was, that is and that will remain for ever)
- Ibere ati opin,(The Alpha and omega)
- OBA AKIKITAN,(Eternity will not be enough to praise and honour you, O Lord)
Please share this information with your friends. Thanks