Home Music Ijoba a Re De by Sola Allyson

Ijoba a Re De by Sola Allyson

0
Ijoba a Re De by Sola Allyson
Ijoba a Re De by Sola Allyson
Advert Download Button

Sensational music worshipper and song leader Sola Allyson released a powerful single melody tagged IJOBA A RE DE from her just released 2021 album titled ISODOTUN. This is a melody that is set to establish the kingdom of God on earth. Download the song below and please share with family and friends.



Sola Allyson — Ìjọba Rẹ Dé Lyrics
Ijoba re de ase re bere
Ijoba re de ase re bere
Agbara wa oba sori mi Ijoba re de ase re bere

Ijoba re de ase re bere
Ijoba re de ase re bere
Agbara wa oba sori mi Ijoba re de ase re bere

call: ijoba re de
resp: Ijoba re de ase re bere (Ijoba ola, Ijoba agbara, Ijoba alafia)
Ijoba re de ase re bere
Agbara wa oba sori mi Ijoba re de ase re bere
Ijoba re de ase re bere
Ijoba re de ase re bere
Agbara wa oba sori mi Ijoba re de ase re bere

Iranwo wa sori isedami
Ijoba re de ase re bere (ijoba riri iranwo nitemi)
Ijoba re de ase re bere
Agbara wa oba sori mi Ijoba re de ase re bere
Ogbemi wo bi aso
Benani oro re losobe
Mokele oro re

Ijoba re de ase re bere
Ijoba re de ase re bere
Agbara wa oba sori mi Ijoba re de ase re bere

Okunkun tan imole de
iranwo de
iranwo
Gbogbo ise n gun mi lowo
Okunkun tan imole de
iranwo de
iranwo
Gbogbo ise n gun mi lowo

Ijoba a Re De — Sola Allyson (Lyrics)

ise mowa nse ise imole
masaseye mari arin to marin arinye
Agbara wa oba sori mi

Okunkun tan imole de
iranwo de
iranwo
Gbogbo ise n gun mi lowo
Okunkun tan imole de
iranwo de
iranwo
Gbogbo ise n gun mi lowo

ise mowa nse ise imole
masaseye mari arin to marin arinye
Agbara wa oba sori mi

Mo fewu sola
benalori
Mofebunmi fogo foluwa tolebun mi
Bena lori
Ijoba re de o
Owo yi da lori ise mi
Ase re latorun bere be nani
Owo yi da lori ise mi

Isodotun de bami nirin ajo mi
bena lori
iranwo latori gun merin agbaye
bena lori
awon toma gbemi mogbekari
bena lori
Ijoba re de o
Owo yi da lori ise mi
Siti anu
Owo yi da lori ise mi
Aye mi abu ola fun o
bena lori

Moti di omo
bena lori
Agbara wa oba sori mi


Join our WhatsApp GROUP or TELEGRAM CHANNEL for instant updates

Leave A Reply

Please enter your comment!
Please enter your name here