Home Music Agbonmagbe by Sola Allyson

Agbonmagbe by Sola Allyson

0
Download Agbonmagbe by Sola Allyson
Advert Download Button

Download Agbonmagbe by Sola AllysonDownload Agbonmagbe by Sola Allyson

Contemporary worship Ace, songwriter and Nigerian talented music minister Sola Allyson is set to drop her new powerful melody titled Agbnmagbe from her 2021 album ISODOTUNAvailable on all digital platforms here.

Sola Allyson — Agbonmagbe (Lyrics)
Chorus:
Agbonmagbe ni ore latodo oluwa
Resp: Agbonmagbe ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe ni ore latodo oluwa
Resp: Agbonmagbe ni ore latodo oluwa
Eni pase ore ti o le tan loluwa
resp: Eni pase ore ti o le tan loluwa
Nibo lore ti nwa bi osodo baba wa
resp: Nibo lore ti nwa bi osodo baba wa
Agbonmagbe ni ore latodo oluwa
Resp: Agbonmagbe ni ore latodo oluwa

Pro Chorus
All: Agbamagbe lokun Agbomagbe losa
Tori agbonmagbe ni baba to pase won
Agbamagbe lokun Agbomagbe losa
Tori agbonmagbe ni baba to pase won

Verse:
Baba Olore Baba Olore
Baba Olore Baba Olore
Ore ti ose salaye
Ore tiokin tan
odo re ni won ti nwa
Baba agbo n gbe
Koseni to dabi re
Buso buso lore re

talo le bi e lejo
Abubu tan ni
Olola ta le gba
Olore ti o se daye le
Mo paya re oloremi
Ore ti ose diyele
Iwo lo ni lowo
Mopaya re olore agbon gbe

Chorus:
Agbonmagbe ni ore latodo oluwa
Resp: Agbonmagbe ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe ni ore latodo oluwa
Resp: Agbonmagbe ni ore latodo oluwa
Eni pase ore ti o le tan loluwa
resp: Eni pase ore ti o le tan loluwa
Nibo lore ti nwa bi osodo baba wa
resp: Nibo lore ti nwa bi osodo baba wa
Agbonmagbe ni ore latodo oluwa
Resp: Agbonmagbe ni ore latodo oluwa

Pro Chorus
All: Agbamagbe lokun Agbomagbe losa
Tori agbonmagbe ni baba to pase won
Agbamagbe lokun Agbomagbe losa
Tori agbonmagbe ni baba to pase won

Verse 2 Agbonmagbe — Sola Allyson

Oba to nfuni laye lo
Olu funni taole dilowo
Kari bunkun lo
Ti ole tan laye nbi
iwonikan lo nfunni
eni to nsanu mi
eni to nfunmi ni irowo lo
Fimi han bi tire
Olore agbo ngbe

Mori osupa loke
Orun na oke loti nran
Irawo wa nbe onse tire
Osumare na nfawo sewa
lataye baye won ma tan
won osi letan lailai
ore ti ole tan
ewa ti ole sa
ogo ti ole ti lailai

Iwo nikan loni ogo
Iwo nikan loni ola
mojuba re Olore agbo ngbe
iru ore yi ni mofi irele okan bere
baba gbe ko mi o
asa mawa leto re Olore agbon n gbe

Chorus:
Agbonmagbe ni ore latodo oluwa
Resp: Agbonmagbe ni ore latodo oluwa
Agbonmagbe ni ore latodo oluwa
Resp: Agbonmagbe ni ore latodo oluwa
Eni pase ore ti o le tan loluwa
resp: Eni pase ore ti o le tan loluwa
Nibo lore ti nwa bi osodo baba wa
resp: Nibo lore ti nwa bi osodo baba wa
Agbonmagbe ni ore latodo oluwa
Resp: Agbonmagbe ni ore latodo oluwa

Pro Chorus
All: Agbonmagbe lokun Agbomagbe losa
Tori agbonmagbe ni baba to pase won
Agbamagbe lokun Agbomagbe losa
Tori agbonmagbe ni baba to pase won

Chorus: Agbonmagbe — Sola Allyson

Agbonmagbe ni ore latodo oluwa
Resp: Agbonmagbe ni ore latodo oluwa
baba olore agbo ngbe
ore towa lodore kole ta lailai
Resp: Agbonmagbe ni ore latodo oluwa
Eni pase ore ti o le tan ni o baba mi o
resp: Eni pase ore ti o le tan loluwa
From the North from the easth from the west from the south
resp: Nibo lore ti nwa bi osodo baba wa
Ila orun iwo orun ariwa ati gunsun
Gbogbo ore latido re ni oluwa
Resp: Agbonmagbe ni ore latodo oluwa

Pro Chorus
All: Agbonmagbe lokun Agbomagbe losa
Tori agbonmagbe ni baba to pase won
Agbamagbe lokun Agbomagbe losa
Tori agbonmagbe ni baba to pase won


Join our WhatsApp GROUP or TELEGRAM CHANNEL for instant updates

Leave A Reply

Please enter your comment!
Please enter your name here